Chorus:
Jesu Jesu Jesu Oruko Re ti niyi to ni gbogbo aye e
Jesu Jesu Jesu Oruko Re ti niyi to ni gbogbo aye
Verse 1:
Ko s'elomiran bi tire, mo f'aye mi si kawo Re
Jo fami mora si 'fe Re, Iwo ni ngo sin titi lai
Verse 2:
Iwo lol'Oluwa gbogbo aye, Ijoba Re ko nipekun
Iseun ife Re ko niwon, jekin le joba pelu Re
Oruko Re ti niyi to
Oruko Re ti niyi to
Oruko Re ti niyi to ni gbogbo gbogbo aye
The video below is a demo version of the song. In a later post I will upload other versions.
Be blessed as you listen.
"the best Praise and Worship on earth is just a rehearsal to the real praise and worship in heaven, try to make it to heaven for that everlasting praise and worship... Sam Onyaiteru"
Hello, good day.
ReplyDeletePlease can you provide the details of this song? I'd like to know the following;
i. who sang the song?
ii. on what occasion?
iii. and the year the song was released
Thank you in anticipation.